Friday special : The "oriki" of Ibadan (video and written)
For two Fridays we have looked at the rise and fall of the great Oyo Empire. So, these week
we are ending it with the Ibadans "oriki"
Ibadan mesi Ogo, nile Oluyole.
Ilu Ogunmola, olodogbo keri loju ogun.
Ilu Ibikunle alagbala jaya-jaya.
Ilu Ajayi, o gbori Efon se filafila.
Ilu Latosa, Aare-ona kakanfo.
Ibadan Omo ajoro sun.
Omo a je Igbin yoo,fi ikarahun fo ri mu.
Ibadan maja-maja bii tojo kin-in-ni, eyi too ja aladuugbo gbogbo logun, Ibadan ki ba ni s’ore ai mu ni lo s’ogun.
Ibadan Kure! Ibadan beere ki o too wo o, Ni bi Olè gbe n jare Olohun.
B’Ibadan ti n gbonile bee lo n gba Ajoji.
Eleyele lomi ti teru-tomo ‘Layipo n mu.
Asejire lomi abumu-buwe nile Ibadan.
A ki waye ka maa larun kan lara, Ija igboro larun Ibadan.
Follow @TwitterDev

Reviewed by h
on
15:29
Rating:
No comments: